Akebaje Lyrics

Lyrics
My ti dagba, mo ti balaga O to ki n gbeyawo
Mo ba ni ki n mu Baby dele
Olulufe mi o, Ajebota pata, Akebaje, omo ti rindin pata
Instrumentation
Ko ma le gunyan, mo ra pounder
Ko le lota, mo ra blender
Ko ma le sebe, mo gba cook

Akebaje o le gbale, mo ra basket
Ko le foso, mo gba dry cleaner
Ko ma le toju omo o, mo gba nani
Anise,
Kole gunyan, mo ra pounder
Ko le lota, mo ra blender
Ko le sebe, mo gba cook
Ko ma kuku se pe Ko le sebe rara
Amo kaka ki n jejekuje, ma ya p'ebimora
Akebaje s'ebe eran, Aja gan o le fije
Ee ehh! nje ko ti fali pata
Instrumentation
Nje e ma woye pe Akebaje useless
E lo ye ki n fi sile komalo
Oti ooooooo
Nnkan kan wa t'akebaje mo se, iyen si te mi l'orun pata pata
Instrumentation
Eni to sedanwo, to gba 1/10, Ah! Edakun, nje Ko ti feli pata
Sugbon wanlokan yen t'akebaje gba Iyen lo se pataki pata
Nnkan kan soso se, t'akebaje mo se, iyen si temilorun patapata
Instrumentation
Writer(s): Ologunde Abisade
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Was als nächstes?

Dein Karma steigt mit jedem Klick! Teile den Guru-Link und bring Lyrics in die Welt.

Lagbaja - Akebaje
Quelle: Youtube
0:00
0:00